Imǫlárá wá kí o lọ
Mimi Werna
Joe Werna

Ada n kasi nigba tio gbo itan tio kpani lerin


Oon rerin


Kini Ada rilara?
 

1

ikųnsinu nse Gisa.


O foju rán


Kilo dé tio fi ni inira?

2

Yuadoo 
ón bęru okukun


Gbogbo eniyan bęru ni gbami


Sugbon Yuadoo le toro fun iranlǫwó

3

Chidubem boju nkpa isę ilé-iwé


Óle sofun ólukǫ


Óle toro fun iranlǫwó

4

Lushan séré kakiri!


Óda ngba mi lati ma wuwa aimǫgbǫnwa

5

Eruro ni ibanuję


Oda lati ké


imǫlárá wá kí o lọ

6

Inu Ayator dun gaani


Arákunri Oni áyǫ


imǫlárá wá kí o lọ

7

Hadizá ǹ sųnmí


Arabinrin na ni lati wa nko sé

8

Ayó ǹ binu


Arakunrin ni Ibanuję


Ibinu nirálá

9

Inu Labake dún


Ki lofa idinu rę


Iya re sé onje tio féran  ju

10

Orun kun Zege


Ore árákunrin gán


Sugbon e duro n, se orun je imǫlárá? Efe béré

11

Efe dojurú!


Sé olé da un ibéré ę

12

Oya Tega lęnú


Arakunrin gbǫ ófófó


Se loto ni?

13

Ará Yebo oyá


Arabinrin koru


Arabirin ni lo ogun ati isimi ki ara fi bale

14

Sekyen ni itelorun


Arabinrin ti pari isę re


Ni siyin 
ole séré

15

Vandefan ko ni isę loni


Onoka le meji soke fun sekyen


Ise réré, ni siyin ja séré! lo sǫ

16
You are free to download, copy, translate or adapt this story and use the illustrations as long as you attribute in the following way:
Imǫlárá wá kí o lọ
Author - Mimi Werna
Translation - Bright Omonikhe, Francisca Ofodile, Oluwatosin Akobe, Taiye Abenu, Tony Okuagu
Illustration - Joe Werna
Language - Yoruba
Level - First sentences