Porridge
Zimbili Dlamini
Catherine Groenewald

Zama wa ni setan lati lọ si ile-iwe.

1

Baba ṣe alabirin fun ounjẹ owurọ.

2

"Mama ni o ṣe porridge ti o dun gaan ju gbogbo porridge lo!" Zama sọ.

3

Porridge yen fun laaye Zama lati ṣe atunse ṣaaju ki o to lọ si ile-iwe.

4

Porridge ti jina.

5

Baba n tú wara pẹlu ife.

6

"Baba, Emi o ro pe suga wa to ninu porridge yi," Zama sọ.

7

Porridge ti mama maa n se da ju oun yi ti baba se.

8

"Baba, ṣe mo le ri suga diẹ sii?" Zama beere

9

Baba fun Zama suga die

10

"Berk, Baba, iwọ fi iyọ sinu porridge mi!"

11

"Baba, nigbawo ni mama n bo si le" Zama beere.

12
You are free to download, copy, translate or adapt this story and use the illustrations as long as you attribute in the following way:
Porridge
Author - Zimbili Dlamini, Hlengiwe Zondi
Translation - Seundede Kubeyinje
Illustration - Catherine Groenewald
Language - Yoruba
Level - First words